?l?run ni Olùpam?? R?

?l?run ni Olùpam?? R?

by Philip O Akinyemi
?l?run ni Olùpam?? R?

?l?run ni Olùpam?? R?

by Philip O Akinyemi

eBook?l?run ni Olùpam?? R? (NOOK Kids - ?l?run ni Olùpam?? R?)

$2.99 

Available on Compatible NOOK Devices and the free NOOK Apps.
WANT A NOOK?  Explore Now

Related collections and offers


Overview

Awọn itan Bibeli ti inu iwe yi yio jẹ iranwọ fun awọn ọmọde lati mọ pe (ranti pe) ohunkohun yo wu ti ńsẹlẹ ninu aiye wọn tabi ni ayika wọn, Ọlọrun ntọju, bẹni O si ńsọ wọn lọsan ati loru. Ko dabi awọn obi wa, Ọlọrun ki i sun tabi ko sarẹ. Ọlọrun si mọ ọjọ waju. O jẹ olododo ati Ẹniti ńpa adehun Rẹ mọ.


Product Details

ISBN-13: 9780997923889
Publisher: FMP365
Publication date: 09/05/2019
Series: ?l?run ni Olùpam?? R? , #1
Sold by: Barnes & Noble
Format: eBook
Pages: 32
File size: 31 MB
Note: This product may take a few minutes to download.
Age Range: 3 Months to 11 Years
Language: Yoruba

About the Author

Dr. Philip O. Akinyẹmi jẹ ọmọ ẹgbẹ awọn ti ńkọ iwe ati aworan fun awọn ọmọde ti ańpe ni (Society of Children's Book Writers and Illustrators - SCBWI). O ńgbe ni ipinlẹ Georgia ti America. Ninu awọn iwe ti o kọ ni "The Holy Spirit and Knowing God." Ẹdun ọkan rẹ ni lati mọ Ọlọrun timọtimọ ati lati jẹ ki awọn enia mọ ọ daradara.
From the B&N Reads Blog

Customer Reviews